Postagens

Mostrando postagens de dezembro, 2022

Ẹ kaabọ̀ si ìlú Salvador, Ojogbọ́n Babalawo Ogundeji Ifadamitan Elebuibon!

Imagem
  Mo ki eyin baba mi, mo ki eyin Ìyá mi. Mo ki eyin Ẹgbọn mi ati aburo mi fún ayeye ọdún yìí. Mo b ẹ È ṣ ù Ẹ l ẹ́ gbára,ki ó fún wa ni ọ̀ na ti o dará, ti o si ye kooro. Jẹ́ ki a ki Èṣù ni ṣaaju ki a sọ̀rọ̀ nipa ohunkohun ninu èto wa loni:   Ago, Mo júbà Èṣù Èṣù, Mo júbà Ẹlẹ́gbára ri ajagbọn wa ti o farasin   Araketu náà ti o ń sọ̀rọ̀ ń sọ̀rọ̀ Èṣù jinnijinni Kò gba Laroye!   Mo dúpẹ́ Oluwo Awoosore Ifdamitan Daniel Diniz ti wọn ń pe mi lati kopa ninu ipade yìí.   Emi ni ọmọ Oduduwa. Mo ki yin ọmọ ìyá mi kaakiri àwọn orílẹ̀èdè lagbaye Ẹ ku ọdún tuntun!   Orúkọ̀ mi ni Adelson Adewale de Brito ti ọpọlọpọ ènìyàn mọ̀ si Ọ̀mọ̀wé Adelson tabi Mọ̀wé Adelson tabi Mawo Adelson. Mo ki gbogbo ilé, Ẹ kaasan! Mo ki dọ́kità Ogundeji Ifadamitan Elebuibon Ẹ kaabọ̀ Ojogbọ́n! Mo ki yin Ẹ káàbọ̀ pẹ̀lu inudidun pe Mo lo èdè àwọn Bàbá nlá wa lati ki yin “Ẹ́ káàbọ̀” si ìlú Salvador, Olu-ìlú ipinlẹ̀ Baííà. Ìlú Salvador jẹ́ ìl...