Ijàgbara àwọn ìmale
Iṣẹlẹ iyalẹnu kan ti o ṣẹlẹ ni òwúr ọ̀ ọjọ́ k ẹ ẹdọ́gbọn o ṣù Kinni,Ọdún 1835, ni Ìlú Salvador, olu ìlú ìpinl ẹ̀ Bahia. Ìwà Àìní-ìtẹ́ l ọ́rùn, ìrẹ́jẹ ati aisi idajọ̀ ododo lori òwò ẹrú ń pọ̀ síí lójoojúmọ́. Ni ọjọ́ ta wi yìí, ẹgb ẹ́ta ẹrú kó ori ṣiriṣi ohun ija l ọ si ita gbangba lati ja lori ọ̀rọ̀ òwò ẹrú. Wọn pinnu lati fi opin si èto buruku y ẹ n ti kò ka wọn si ènìyàn. Iṣẹlẹ náà j ẹ́ ijagbára to lokiki jùl ọ ni gbogbo ìpinl ẹ̀ Bahia. Nitori pe púp ọ̀ ninu àwọn ẹrú ti o kopa ninu ìjàgb á ra náà j ẹ́ musulumi, a n pe orúkọ r ẹ̀ ni “ Ìjàgbara àwọn Ìmale” tabi Ìjà àwọn ìmale . “Ìmale” ni orúkọ ti wọn n pe à wọn ẹl ẹ́ sin musulumi ni èdè Ànàgó (tabi èdèYorùbá). Àwọn ọmọ il ẹ̀ Aláwọ̀ dúdú nikan lo jà ijà náà. Àwọn ẹrú ti a bi ni Ìlú Brasili, ti a pe ni “ àwọn Kreoles ”, kò l ọ w ọ́ si .