Ijàgbara àwọn ìmale

 


Iṣẹlẹ iyalẹnu kan ti o ṣẹlẹ ni òwúrọ̀ ọjọ́ kẹdọ́gbọn oṣù Kinni,Ọdún 1835, ni Ìlú Salvador, olu ìlú ìpinlẹ̀ Bahia.

Ìwà Àìní-ìtẹ́lọ́rùn, ìrẹ́jẹ ati aisi idajọ̀ ododo lori òwò ẹrú ń pọ̀ síí lójoojúmọ́.

 Ni ọjọ́ ta wi yìí, ẹgbẹ́ta ẹrú kó oriṣiriṣi ohun ija lọ si ita gbangba lati ja lori ọ̀rọ̀ òwò ẹrú.

Wọn pinnu lati fi opin si èto buruku yn ti kò ka wọn si ènìyàn. 

Iṣẹlẹ náà jẹ́ ijagbára to lokiki jùlọ ni gbogbo ìpinlẹ̀ Bahia.

Nitori pe púpọ̀ ninu àwọn ẹrú ti o kopa ninu ìjàgbára náà jẹ́ musulumi, a n pe orúkọ rẹ̀ ni “Ìjàgbara àwọn Ìmale” tabi Ìjà àwọn ìmale.

 “Ìmale” ni orúkọ ti wọn n pe àwọn ẹlẹ́sin musulumi ni èdè Ànàgó (tabi èdèYorùbá). 

Àwọn ọmọ ilẹ̀ Aláwọ̀ dúdú nikan lo jà ijà náà. Àwọn ẹrú ti a bi ni Ìlú Brasili, ti a pe ni “àwọn  Kreoles”, kò lwọ́ si


Comentários

Postagens mais visitadas deste blog

Ẹ kaabọ̀ si Kilombo Kingoma náà, akọkọ ilẹ̀ ibilẹ̀ Afirika ni okeere

Ìtàn òrìṣà Ṣàngó ti a ranti nínú ìjọsìn wa apa keji

Ògún Lakaye Osìn imọlẹ̀