Postagens

Mostrando postagens de agosto, 2021

Loni ni Ọjọ́ a nṣe àjọ̀dún Òrìṣà Ọbalúwaye

Imagem
Ẹ kúu déédéé àsikò yìí, ọmọ Oduduwa àtàtà kakiri agbaye Orúkọ tèmi ni Oluk ọ̀ Agba Adelson de Brito ti ọpọ eeyan m ọ̀ sí Mawo Adelson. Olori ẹsin ibilẹ̀ Òrìsà àti Vodun ti Afirika ni mi Olukọ Èdè àti àṣà Yorùba-Ànàgó ni mi. Ọmọ ọmọ ènìyàn Ànàgó ti wọ́n bi àti dagba ni Ilẹ̀ okeere ni mi. Àwọn obi mi bi mi ni Ìlú Salvador, Olu-ilu ipinlẹ̀ Baííà, ni orílẹ̀-èdè Burasili. Mo s ọ pẹ̀lú gbogbo yín lati ìlú yìí ni bayìí. Inu mi dun gan Ope lowo Eledumare Gbogbo irunmale ti ile Oduduwa fún mi anfaani yii, lati kopa ni eto yii, po pelo Ojogbon Mateus Aleluya Ṣe o mọ wipe ni Ìlú mi àwọn aláwọ̀ dúdú pọ̀ júlọ agbaye lẹhin Afirika? O ṣ ee ṣ e ti o mo wípè eya Ánàgó jẹ́ àw ọ n ọm ọ Oduduwa ti a ji lati agbegbe ti iwoorun il ẹ̀ aláwo dúdú, nipasẹ àwọn oniṣowo ẹrú lakoko iṣowo ẹrú? Se o mo wípè Gbogbo ijọsin Ọlọ́run ni imisi Eleduwa ni o si ni ere fún ẹ̀kọ́, fún ajọṣe, fún ikọ́ni ti o wa ninu òdodo? Bẹẹni, ẹyin ọmọ, kò si Igbagbọ akọkọ ati alailẹgbẹ ati iyas...

Irohin nipa Orin Òrìṣà 1

Imagem
  Ẹ ku deedee asiko yìí eyin ọmọ Ànàgó atata ! O ma tọjọ́ mẹ́ta o! Ṣe o mọ̀ wípè ni aye atijọ́, làkókò oko ẹrú ni ìlú yi, àwọn ọmọ káàrò-oòjíire lò èdè kanna fún ibaraẹninsọ̀rọ̀ laarin ara wọn? Wọn a pè ara wọn “Ànàgó”, àwọn ènìyàn miran tún pè èdè wọn “èdè Ànàgó” abi “èdè Nàgó”, abi “Nàgó. A kò gb ọ́ dọ̀ gbàgbé pe o ṣ e pàtàkì ki a lugbadi ohun ti o j á kiri oríl ẹ̀ -èdè agbaye bayii o, am ọ́ n, ẹ jẹ́ ki a pa ofin im ọtoto m ọ , ki a sì yàgò fún ipéj op ọ̀ ti o ba jù iye ti ij ọ ba ipinl ẹ̀ s ọ l ọ , aabo àw ọn irunmalẹ ti il ẹ̀ Oduduwa yoo daju lori gbogbo wa o. Eyin ọm ọ mi oluf ẹ , Mo wa de níbí yìí loni nitori pe mo fẹ́ s ọ nipa orin Òrì ṣ à. Ni Ọj ọ́ Rírú to k ọ ja ni, w ọ́ n a ń pe mi sì ayẹyẹ ibimọ Òrì ṣ à túntún kan. A korin ọpọlọpọ à wọn orin fún iyin Òrìṣà O ṣ óòsi, ṣ ùgb ọ́ n, o kò y ẹ mi ohun ti w ọ́ n ń korin. Eyi ti ṣe aniyan mi nigbagbogbo laarin igbesi aye mi. Mo bòwò fún iṣẹ ti àwọn babanla w...