Ẹ kaabọ̀ si Kilombo Kingoma náà, akọkọ ilẹ̀ ibilẹ̀ Afirika ni okeere
Ìlú wo lo gb ọ Yorùbá jùl ọ ni oríl ẹ̀ èdè Brasil? Ìlú náà ti ọ̀pọ̀ ènìyàn ń pé ní ìlú Bahia. Orúkọ̀ mi ni Adelson Adewale de Brito ti ọpọlọpọ ènìyàn mọ̀ si Ọ̀mọ̀wé Adelson tabi Mọ̀wé Adelson tabi Mawo Adelson. Mo ki gbogbo ilé, Mo ki awon baba nla wá, Mo ki, awon Ìyá nlá wa. Oduduwa Mo juba! Mo ki awon omo iya fún ajoyo yìí. Mo b ẹ È ṣ ù Ẹ l ẹ́ gbára, ki ó fún wa ni ọ̀ na ti o dará, ti o si ye kooro. Jẹ́ ki a ki Èṣù ni ṣaaju ki a sọ̀rọ̀ nipa ohunkohun ninu èto wa loni: Ago, Mo júbà Èṣù,Èṣù, Mo júbà Mo ki Ẹlẹ́gbára ti won ri ajagbọn wa ti o farasin Araketu náà ti o ń sọ̀rọ̀ ń sọ̀rọ̀ Èṣù jinnijinni Kò gba Laroye! Ni ọjọ́ m ọ kandinlogun o ṣ ù Ẹrẹ́nà yìí lára abẹwo ìgbà keji si orílẹ̀-èdè Brasil, Ọọ̀ni Ile-Ifẹ náà, Ọba Adeyẹye Ogunwusi Ọjaja keji wa si ìlú Lauro de Freitas ni ipinl ẹ̀ Bahia lati s ọ̀ Kilombo Kingoma náà lel ẹ̀ g ẹg ẹ bi ak ọkọ il ẹ̀ ibil ẹ̀ Afirika ni okeere. Ni oruko temi ati loruko gbogbo ọmọ ìlú Lauro de Freita...